1. “A kò gbọdọ lo ẹsìnláti fa
ìyapa, láti fi ìyà jẹni, tàbiláti
lo àǹfàní tí kò tọ”
4th
January, 2015
“Orílẹ-èdè Nàìjíríà tí a ni lọkàn jẹ èyí tí
gbogbowa á le jọjòkó ƴọayọ ìdùnnú, kí
á dì jọdúpẹ lọwọ Olọrunpapọ. Bí ó ti yẹ
kí ó rí nìyẹn”
4th
January, 2015
“Ojúṣe ìjọba ni láti pèsè ààbò àti
ìfọkàn balẹ fún gbogboọmọ Nàìjíríà
láìfi ti ẹsìn, ẹyà àti èdè ṣe. Ohùn tí a
gbọdọ pawọpọ ṣe ni, ní pàtàkì jùlọ ní
ọjọ òní tí à ń ṣe ìdúpẹ”
4th
January, 2015
“Ìgbàgbọ mi láti ìbèrè ayé mí ni wípé
gbogbo ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà
gbọgbọ ní òmìnira ẹsìn láti sin Ọlọrun
gẹgẹ bí ìgbàgbọ wọn”
4th
January, 2015
“Ojúṣe ìjọba kìí ṣe ti ẹsìn”
4th
January, 2015.
Buhari
Nípa Èsìn
www.actnow.ng
“Inú mi dùn láti ríi wí pé ìsìn ìdúpẹ
ọlọdọọdún yìí, bí ó tilẹ jẹ pé ìsìn ẹsìn
Kírísítéẹnì ni, síbẹ o kó gbogbo ẹlẹsìn
papọ. Kírísítẹnì, Mùsùlùmí àti gbogbo
ẹsìn tí ó kù ni wọn ń darapọ níbí lọdọọdún
láti dúpẹ lọwọ Ọlọrun. Bí ó ṣe yẹ kí ó rí nìyí”
4th January, 2015.
Kín Ni Èrò Bùhárí Nípa Ѐsìn?
“Àwòrán fọnrán tí wọn fi sórí ẹrọ
agbọrọkáyé fi wọn hàn gẹgẹ bíi elérò
kúkúrú. Ó fi irú ènìyàn tí wọn jẹ hàn; irú
wọn kò le ṣẹrù bàwá tàbí dúnkokò mọ
òmìnira wa . Ọrọ ẹnu wọn ti fi hàn
gbangba wí pé wọn kìí ṣe ènìyàn Ọlọrun.
Wọn kò ní èrò rere fún ọrílẹ-èdè wa àti
àwa ènìyàn ibẹ. Mùsùlùmí ni mi. Mo ní
ìmọ ẹsìn kírísítẹnì mo sì mọ wí pé ẹsìn
méjéèjì ń wá àgbéjọpọ àlàáfíà fún ọmọ
ènìyàn”
Vanguard; 8th May, 2014.
2. Ǹjẹ Alákatakítí Ẹsìn Mùsùlùmí Tí Ó Fẹ Sọ
Orílẹ-èdè Nàìjíríà Di Ẹlẹsìn Mùsùlùmí ni
Buhari?
Ní nǹkan bíi ọdún márùn-ún sẹyìn ni wọn bẹrẹ sí ní fi
ẹsùn kan Ọgágun Muhammadu Buhari wí pé alákatakítí
ẹsìn Mùsùlùmí ni àti wí pé ó fẹ sọorílẹ-èdè yìí di ti ẹlẹsìn
Mùsùlùmí. Ẹ jẹ kí á wo àwọn òtítọ tí ó fi ojú hàn:
Òtítọ Ibẹ
• Bùhárí kò fi ìgbà kan sọ wí pé òun á mú ìṣèjọba nira
fún ìjọba ilẹ Nàìjíríà.
• Ọkan nínú àwọn Olóyè Ẹgbẹ PDP Alhaji Lawal Kaita
ló sọ wí pé ìsàkóṣo ìjọba ilẹ Nàìjíríà á nira látiṣe lẹyìn
ìdìbò ọdún 2011.
• Irọ ni Rueben Àbàtì tí ó jẹ amúgbálẹgbẹẹ Ààrẹ lórí
ètò Ìròyìn pa wí pé Bùhárí ló sọbẹẹ.
Kín Ni Bùhárí Ṣe Nípa Irọ Àbàtì Yìí?
• Bùhárí pe Àbàtì àti ìwé Ìròyìn Guardian (tí ó
tẹìròyìnnáà jáde) ní ẹjọ ìbanilórukọjẹ sí ilé ẹjọ gíga
(ṅumber ẹjọ yẹn ni ID837/2011).
• Bùhárí gbà láti gbé ẹjọ kúrò nílé ẹjọ nítorí pé
Jonathan bẹ Bùhárí.
• Ní ọjọ Kọkànlá Oṣù Keje ọdún 2013 (11-7-2013) ìwe]
ìròyìn Guardian tẹ àtẹjáde níbití Àbàtì tigbà wí pé
irọ niòun pa mọ Bùhárí, ó sì tọrọ àforíjì.
Ǹjẹ Bùhárí kórìíra àwọn ẹlẹsìn mìíràn?
• Nígbà tí ó jẹ olórí orílẹ-èdè yìí, mọkànlá (11) nínú
àwọn Gómìnà mọkàndínlógún (19) tí ó yàn sí ipò
Gómìnà, ẹlẹsìn Kírísítẹẹnì niwọn. Púpọ nínú àwọn tọ
ń bá Bùhárí siṣẹ àti àwọn òsìṣẹ inú ilé rẹ, kírísítẹẹnì
niwọn.
• Bùhárí nígbàgbọ wí pé kò yẹkí orílẹ-èdè Nàìjíríà fi
aramọ ẹsìn kan ṣoṣo, dípò bẹẹ, kí á fi ààyè gba
olúkálukú láti ṣe ẹsìntí ó bá fẹ. Torí ìdí èyí ló ṣe kọ
láti jẹ kí Orílẹ-èdè Nàìjíríà darapọ mọ ẹgbẹ
Orílẹ-èdè Ẹsìn Mùsùlùmí Agbaiyé (OIC).
Bùhárí kò kórìíra àwọn tí kìí ṣe
ẹlẹsìn Mùsùlùmí!
Olórí tí ó fi ọkàn sin ọrílẹ-èdè Nàìjíríà ni. Ó kó ènìyàn
mọra, ó sì tisiṣẹ pọ pẹlú ọpọlọpọ ọmọ Nàìjíríà láìfi ti
ẹsìn tàbí ẹyà ṣe. Àwọn olórí méjì tí ó súnmọ Bùhárí
dáadáa ni Ọgágun Yàkúbù Gowon àti Theophilus
Danjuma GCON. Ẹlẹsìn Kírísítẹnì ni àwọn méjéèji, wọn
sì wà láyé, ẹnití ó bá fẹ mọ òtítọ bóyá alákatakítí ẹsìn
Mùsùlùmí n iBùhárí tàbí bẹẹ kọ, kí ó lọbí wọn.
Kín Ni Bùhárí Sọ Nípa Boko Haram?
“Ìwà ìkà nikí á máa fi àdó olóró pa ènìyàn ní
gbogbo ìgbà. Ó burú jáì láti huirú ìwà yìí lọjọ
ọdún Kérésì, gbogbo ẹni tó bá nífẹẹ àlàáfíà ló
yẹkí ó bu ẹnuàtẹ lu iwà ìkà yìí, kí wọnsì bèèrè
fún wíwá àwọn ọdaràn wọnyí kànláti fi wọn
jófin” Ìwé Ìròyìn
This Day Life; 26th December, 2012.
“N kò mọ ọmọ ẹgbẹ Boko Haram
Kankan. N kò gbàgbọ nínú ìpànìyàn,
n kò sì mọ ẹsìn Kankan tí á lọ pa
ènìyàn, sun ilé-ẹkọníná”
Punch 8th November, 2012
Kínṅi Ó Yẹ Kí O jẹ Ojúṣe
Àwọn Olórí Ẹsìn?
SỌ ÒTÍTỌ!!!
“ahọn gbogbo àwọn wòlíì orílẹ-èdè yìí gbọdọ tú,
gbogbo àwọn ẹnu tí a ti padé gbọdọ là, bí wọn bá ti
pa ọ lẹnumọ, pọ ohun tí wọn fi dí ọ lẹnu kí o sọrọ
nítorí ọjọ iwájú àwọn ọmọ wa - - Bí jíjẹ olórí bàbá mi
bá máa mú ìparun bá àwọmọmọ, jẹ kí àjòjì kúkú ṣe
olórí kí ìran wasì wà”
“Bí baba bá ń jẹ àjẹyó, tí ebi sì ń pa àwọn ọmọ,
ǹjẹ irú ẹni bẹẹ yẹní gégé baba bi?”
RevF.R. Ejike Mbaka 31st December, 2014
“Àwọn Olùsọ Àgùtànkan ń jẹ àṣáró Jákọbù,
wọn sì ń ta àsọtẹlẹ wòlíì: wọn ń fi ìfàmìòróró
yàn se òwò ní Aso Rock --- àwọnkanń gbé
owó ilẹ wa, wọn ń sọ ọ di owó Dọlà nínú
ọkọ òfurufú aládàáni, wọn ń gbé e jáde
lọkùrò lórílẹ-èdè”
Rev F.R. EjikeMbaka 31st December, 2014